Baba, mo n’ owo mi si O
1. Baba, mo n’ owo mi si O;
Nko mo ‘ranwo miran:
Bi O ba kuro lodo mi,
A! nibo ni ngo lo?
Nko mo ‘ranwo miran:
Bi O ba kuro lodo mi,
A! nibo ni ngo lo?
2. Ohun t’ OmoRe f’ ara da
Ki nto la ‘ju s’ aiye!
Ise t’ O se lati gba mi
Lowo ‘ku ailopin!
Ki nto la ‘ju s’ aiye!
Ise t’ O se lati gba mi
Lowo ‘ku ailopin!
3. Orisun ‘gbagbo, si O ni
Mo gb’ oju are mi:
Mba je le ri ebun ni gba
Laisi re mo segbe.
Mo gb’ oju are mi:
Mba je le ri ebun ni gba
Laisi re mo segbe.
Tip: double-tap the words (or use ) to show them full screen on a projector or TV.
Sing to the tune of
Any of these hymns' tunes fits YBH 220.
YBH 505 Iku l’ opin ohun gbogbo
YBH 291 A! mba le l’ egberun ahon
YBH 439 Ile-EKO ojo ‘sinmi
YBH 523 Jerusalem ibi ayo
YBH 579 Ko to k’ awon mimo beru
YBH 55 Ninu gbogbo ewu oru
YBH 87 Ayo b’ aiye: Oluwa de!
YBH 350 Jesu wipe k’ a ma sora
YBH 155 Emi orun, gb’ adura wa
YBH 232 Isun kan wa t’o kun f’eje