Baba wa ti o mbe l’ orun
1. Baba wa ti o mbe l’ orun,
Owo l’ oruko Re,
‘Joba Re de, ife Re ni
K’ a se bi ti orun.
Owo l’ oruko Re,
‘Joba Re de, ife Re ni
K’ a se bi ti orun.
2. Fun wa l’ onje ojo loni,
Dari ese wa ji,
Gege bi a ti ndariji
Awon ti o se wa.
Dari ese wa ji,
Gege bi a ti ndariji
Awon ti o se wa.
3. Ma sin wa sinu idanwo,
Yo wa ninu ewu,
Nitori ‘joba ni Tire,
At’ ogo titi lai.
Yo wa ninu ewu,
Nitori ‘joba ni Tire,
At’ ogo titi lai.
Tip: double-tap the words (or use ) to show them full screen on a projector or TV.