Je k’ agb’ oju ayo s’ oke
1. Je k’ agb’ oju ayo s’ oke
Si agbala orun,
K’ a yo lati ri Baba wa
Lori ite ife.
Si agbala orun,
K’ a yo lati ri Baba wa
Lori ite ife.
2. Wa, je k’ a wole l’ ese Re,
K’ a sunmo Oluwa,
Angeli ina tab’ ida
Ki’ so ‘bujoko Re.
K’ a sunmo Oluwa,
Angeli ina tab’ ida
Ki’ so ‘bujoko Re.
3. Jesu s’ ilekun ‘lafia
T’ ayo orun sile,
K’ orin iyin wa ga s’ oke
De ‘te t’ o l’ agbara.
T’ ayo orun sile,
K’ orin iyin wa ga s’ oke
De ‘te t’ o l’ agbara.
4. A m’ opo ope wa fun O,
Alagbawi t’ oke;
Ogo fun Oba t’ o wa lai,
T’o pa ‘binu Re mo.
Alagbawi t’ oke;
Ogo fun Oba t’ o wa lai,
T’o pa ‘binu Re mo.
Tip: double-tap the words (or use ) to show them full screen on a projector or TV.