Gbat’ okan are fe ‘simi
1. Gbat’ okan are fe ‘simi,
T’ o nwa Olorun re,
B’ o ti dun to lati r’ ale
T’ o pin ose lala.
T’ o nwa Olorun re,
B’ o ti dun to lati r’ ale
T’ o pin ose lala.
2. Adun lati r’ oye ‘mole
T’ o la si oju wa,
Nigba oro isokanji
Tan imole titun.
T’ o la si oju wa,
Nigba oro isokanji
Tan imole titun.
3. Sugbon wakati re nsare;
Ki o to de opin,
Emi Mimo masai fun mi
N’ isimi l’ okan mi.
Ki o to de opin,
Emi Mimo masai fun mi
N’ isimi l’ okan mi.
Tip: double-tap the words (or use ) to show them full screen on a projector or TV.