YBH 662

Fun wa n ‘le onigbagbo

Save
1. Fun wa n ‘le onigbagbo
Ile ti a nkeko Bibeli
Ile ta fe se ’fe Oluwa
Tafe wa ife Re de lade
Fun wa n ’le onigbagbo;
Fun wa n ’le onigbagbo
2. Fun wa n ‘le onigbagbo
Ile ti baba jo lotito
Ile to bo lowo asise
Ile ti nyo fun ‘fe at’ayo
Fun wa n ‘le onigbagbo;
Fun wa n ‘le onigbagbo
3. Fun wa n ‘le onigbagbo
Ile ti iya nsakitiyan
Po na Kristi lo daraju
Ile t’o gba Kristi lalejo
Fun wa n ‘le onigbagbo
Fun wa n ‘le onigbagbo
4. Fun wa n ‘le onigbagbo
Ile ti a n to awon ‘mode
Lati mo Kristi to feran won
Ile ti a tan na adura
Fun wa n ‘le onigbagbo
Fun wa n ‘le onigbagbo

Tip: double-tap the words (or use ) to show them full screen on a projector or TV.

My melodies

Found another hymn whose tune fits this one? Save it here so you can sing it again.

Sign in to save melodies
← YBH 661

Sources: acknowledgements.

Take FaceChrist everywhere

Chat, post, meet people and sell from your phone. Get instant alerts for new messages and matches, plus the Bible offline in seven languages.