YBH 637

Ore ni Jesu fun mi, tito ‘b’ Ife Re po

Save
1. Ore ni Jesu fun mi, tito ‘b’ Ife Re po,
Ife nla ti ko le sa,
Bi mo tile s’ aito,
S’ife Re yi ni mo ti se;
Sugbon ngba mo kunle,
Mo jewo gbogb’ aise mi,
Eru ese si bo.
Chorus
Beni Jesu ri, O nle okunkun lo,
Beni Jesu ri, lojojo npa mi mo,
Beni Jesu ri, l’ aginju yi ja,
Gege bi ife nla Re.
2. Nigbat’ okunkun ‘yonu su bo sanma l’ oke
Ti nko le ri Olugbala,
Mo gbagbe ife nla Re;
Lat ite Anu Re l’ orun,
O r’ ainireti mi,
L’anu O m’ awosanma si,
O fi han pe On wa.
Chorus
Beni Jesu ri, O nle okunkun lo,
Beni Jesu ri, lojojo npa mi mo,
Beni Jesu ri, l’ aginju yi ja,
Gege bi ife nla Re.
3. A! mo le Korin titi, orin ife Jesu,
Orin anu itoju Re,
L’or’ elese b’ emi,
Ife nla Re ‘li aiye, igbi lile gboran,
Jesu pase pe “dake je,”
O le okunkun lo.
Chorus
Beni Jesu ri, O nle okunkun lo,
Beni Jesu ri, lojojo npa mi mo,
Beni Jesu ri, l’ aginju yi ja,
Gege bi ife nla Re.

Tip: double-tap the words (or use ) to show them full screen on a projector or TV.

My melodies

Found another hymn whose tune fits this one? Save it here so you can sing it again.

Sign in to save melodies

Sources: acknowledgements.

Take FaceChrist everywhere

Chat, post, meet people and sell from your phone. Get instant alerts for new messages and matches, plus the Bible offline in seven languages.