Olorun so wa n’nu oko
1. Olorun so wa n’nu oko
Larin omi jinjin,
S’ oluso wa bati nwa lo,
Ninu ajin oru.
Larin omi jinjin,
S’ oluso wa bati nwa lo,
Ninu ajin oru.
2. Eru ko ye ki o ba wa,
Larin iji ti nja,
Niwon gba t’ O wa nitsi
Larin omi ti nru.
Larin iji ti nja,
Niwon gba t’ O wa nitsi
Larin omi ti nru.
3. Iparoro ati iji,
T’ o nkoja lori ‘le,
Iwo ni o da gbogbo won,
Nwon wa nikawo Re.
T’ o nkoja lori ‘le,
Iwo ni o da gbogbo won,
Nwon wa nikawo Re.
4. Nigbat’ awon Aposteli,
Wa lori ‘gbi okun,
Ase kan lat’ odo Re wa,
Mu dake roro wa.
Wa lori ‘gbi okun,
Ase kan lat’ odo Re wa,
Mu dake roro wa.
5. Gbati iji to buru ju,
Ba nru l’ atokan wa,
Oluwa ma sai ba wa gbe
F’ alafia ba wa gbe.
Ba nru l’ atokan wa,
Oluwa ma sai ba wa gbe
F’ alafia ba wa gbe.
6. Ninu wahala aiye yi,
Ma se amona wa,
Titi ao fi de ‘le rere,
Nibi t’ ese ko si.
Ma se amona wa,
Titi ao fi de ‘le rere,
Nibi t’ ese ko si.
Tip: double-tap the words (or use ) to show them full screen on a projector or TV.
Sing to the tune of
Any of these hymns' tunes fits YBH 622.
YBH 505 Iku l’ opin ohun gbogbo
YBH 291 A! mba le l’ egberun ahon
YBH 439 Ile-EKO ojo ‘sinmi
YBH 523 Jerusalem ibi ayo
YBH 579 Ko to k’ awon mimo beru
YBH 55 Ninu gbogbo ewu oru
YBH 87 Ayo b’ aiye: Oluwa de!
YBH 350 Jesu wipe k’ a ma sora
YBH 155 Emi orun, gb’ adura wa
YBH 232 Isun kan wa t’o kun f’eje