Ojo ibukun yio si ro!”
1. Ojo ibukun yio si ro!”
Eyi n’ ileri ife;
A o ni itura didun
Lat’ odo Olugbala
Eyi n’ ileri ife;
A o ni itura didun
Lat’ odo Olugbala
Chorus
Ojo ibukun! Ojo ibukun l’ a nfe;
Iri anu wa yi wa ka, sugbon ojo l’ a ntoro.
Ojo ibukun! Ojo ibukun l’ a nfe;
Iri anu wa yi wa ka, sugbon ojo l’ a ntoro.
2. “Ojo ibukun yio si ro!”
Isoji iyebiye;
Lori oke ojo mbo,
Isoji iyebiye;
Lori oke ojo mbo,
Chorus
Ojo ibukun! Ojo ibukun l’ a nfe;
Iri anu wa yi wa ka, sugbon ojo l’ a ntoro.
Ojo ibukun! Ojo ibukun l’ a nfe;
Iri anu wa yi wa ka, sugbon ojo l’ a ntoro.
3. “Ojo ibukun yio si ro!”
Ran won si wa, Oluwa!
Fun wa ni itura didun,
Wa, f’ ola fun oro Re.
Ran won si wa, Oluwa!
Fun wa ni itura didun,
Wa, f’ ola fun oro Re.
Chorus
Ojo ibukun! Ojo ibukun l’ a nfe;
Iri anu wa yi wa ka, sugbon ojo l’ a ntoro.
Ojo ibukun! Ojo ibukun l’ a nfe;
Iri anu wa yi wa ka, sugbon ojo l’ a ntoro.
4. “Ojo ibukun yio si ro!”
Nwon ‘ba je le wa loni!
B’a ti njewo f’ Olorun wa,
T’ a npe oruko Jesu,
Nwon ‘ba je le wa loni!
B’a ti njewo f’ Olorun wa,
T’ a npe oruko Jesu,
Chorus
Ojo ibukun! Ojo ibukun l’ a nfe;
Iri anu wa yi wa ka, sugbon ojo l’ a ntoro.
Ojo ibukun! Ojo ibukun l’ a nfe;
Iri anu wa yi wa ka, sugbon ojo l’ a ntoro.
Tip: double-tap the words (or use ) to show them full screen on a projector or TV.