Tani yio gbe Jabob’ dide?”
1. Tani yio gbe Jabob’ dide?”
Ore Jakob’ ko po;
Eyi t’ o je ‘yanu ni pe,
Imo won ko s’ okan.
Ore Jakob’ ko po;
Eyi t’ o je ‘yanu ni pe,
Imo won ko s’ okan.
2. "Tani yio gbe Jakob’ dide?”
Ota Jakob’ n’ ipa;
Mo r’ ayo ‘segun l’ oju won,
Nwon ni o pari fun.
Ota Jakob’ n’ ipa;
Mo r’ ayo ‘segun l’ oju won,
Nwon ni o pari fun.
3. “Tani yio gbe Jakob’ dide?”
A ha r’ eni le wi?
Eka t’ o ro nibule yi
O ha tun le ye mo?
A ha r’ eni le wi?
Eka t’ o ro nibule yi
O ha tun le ye mo?
4. Oluwa mi, ise Re ni!
Ko s’ emi t’ o le se;
Se b’ iri s’ ori Jakobu,
On yio si tun ye.
Ko s’ emi t’ o le se;
Se b’ iri s’ ori Jakobu,
On yio si tun ye.
Tip: double-tap the words (or use ) to show them full screen on a projector or TV.