Orisun lai, t'ayo gbogbo
1. Orisun lai, t'ayo gbogbo,
Ki iyin Re gba enu wa,
Nigbat'a wa sinu ‘le Re,
'Wo-t'ore Re buk’ buk'odun
Ki iyin Re gba enu wa,
Nigbat'a wa sinu ‘le Re,
'Wo-t'ore Re buk’ buk'odun
2. Bi aiye yi ti tobi to,
Owo Re l'od'opo re mu
‘Wo l'o ko orun lati ran,
L'o ko okunkun lati su.
Owo Re l'od'opo re mu
‘Wo l'o ko orun lati ran,
L'o ko okunkun lati su.
3. Itana yo li ase Re,
Ododo se ile l'oso,
Orun si san l'akoko re,
Lati m'ohun ogbin dagba.
Ododo se ile l'oso,
Orun si san l'akoko re,
Lati m'ohun ogbin dagba.
4. L'akoko ‘kore owo Re
Tu onje ka s'ile gbogbo,
Otutu ko si n'ipa kan
Nigbati itoju Re wa.
Tu onje ka s'ile gbogbo,
Otutu ko si n'ipa kan
Nigbati itoju Re wa.
5. Jek'a f'ayo sin Olorun,
L'owuro ati l’ l'asale,
Orin ayo ye fun ojo,
Ose, osu ati odun.
L'owuro ati l’ l'asale,
Orin ayo ye fun ojo,
Ose, osu ati odun.
Tip: double-tap the words (or use ) to show them full screen on a projector or TV.