YBH 353

Ema te siwaju, Kristian ologun

Save
1. Ema te siwaju, Kristian ologun,
Ma tejumo Jesu t’ O mbe niwaju
Kristi Oluwa wa ni Balogun wa,
Wo! asia Re wa niwaju ogun;
Chorus
E ma te siwaju, Kristian ologun,
Sa tejumo Jesu t’ O mbe niwaju.
2. Ni oruko Jesu, ogun esu sa,
Nje Kristian ologun, ma nso s’ isegun;
Orun apadi mi ni hiho iyin,
Ara, gb’ ohun nyin ga, gb’ orin nyin s’ oke;
Chorus
E ma te siwaju, Kristian ologun,
Sa tejumo Jesu t’ O mbe niwaju.
3. Bi egbe ogun nla, n’ Ijo Olorun,
Ara, a nrin l’ ona t’ awon mimo rin;
A ko ya wa n’ ipa, egbe kan ni wa,
Okan l’ eko, n’ ife ati n’ ireti.
Chorus
E ma te siwaju, Kristian ologun,
Sa tejumo Jesu t’ O mbe niwaju.
4. Ite at’ ijoba wonyi le parun,
Sugbon Ijo Jesu y’o wa titi lai,
Orun apadi ko le bor’ Ijo yi,
A n’ ileri Jesu, eyi ko le ye.
Chorus
E ma te siwaju, Kristian ologun,
Sa tejumo Jesu t’ O mbe niwaju.
5. E ma ba ni kalo, enyin enia;
D’ ohun nyin po mo wa, l’ orin isegun,
Ogo, iyin, ola, fun Kristi Oba,
Eyi ni y’o ma je orin wa titi.
Chorus
E ma te siwaju, Kristian ologun,
Sa tejumo Jesu t’ O mbe niwaju.

Tip: double-tap the words (or use ) to show them full screen on a projector or TV.

My melodies

Found another hymn whose tune fits this one? Save it here so you can sing it again.

Sign in to save melodies

Sources: acknowledgements.

Take FaceChrist everywhere

Chat, post, meet people and sell from your phone. Get instant alerts for new messages and matches, plus the Bible offline in seven languages.