YBH 348

Ajagun Jesu l’ emi bi

Save
1. Ajagun Jesu l’ emi bi,
At’ omo ehin Re?
Ngo ha beru lati wasu
Agbara isin Re?
2. Ao ha gbe mi g’ oke orun
Lori ‘busun ‘rorun,
Gbati opo ja f’ ere na
Lori okun eje?
3. Ko ha s’ ota lati ba ja?
Ti mo ni lati ko?
Aiye ha ba or’-ofe t’y’o
Mu mi d’ oro Re je?
4. Mo ni ja bi ngo ba joba;
Oluwa, pelu mi;
Ngo f’ ara da gbogbo ise,
Pelu iranwo Re.
5. B’ awon enia Re tile ku,
Nwon o segun ‘ja na,
Nwon ri isegun l’ okere,
Eru ko si ba won.
6. Gb’ ojo t’ o l’ ogo ni ba de,
T’ awon ogun Re ndan;
Ninu aso ‘segun l’ oke,
Ogo yio je Tire.

Tip: double-tap the words (or use ) to show them full screen on a projector or TV.

My melodies

Found another hymn whose tune fits this one? Save it here so you can sing it again.

Sign in to save melodies

Sources: acknowledgements.

Take FaceChrist everywhere

Chat, post, meet people and sell from your phone. Get instant alerts for new messages and matches, plus the Bible offline in seven languages.