YBH 327

Isimi wa l’ orun, ko si l’ aiye yi

Save
1. Isimi wa l’ orun, ko si l’ aiye yi,
Emi o se kun, ‘gbat’ iyonu ba de;
Simi okan mi, eyikeyi t’ o de,
O dun ajo mi ku, o mu k’ ile ya.
2. Ko to fun mi kin ma simi nibi yi,
Ki nsi ma ko le ‘le mi ninu aiye yi;
Ongbe ilu t’ a ko f’ owo ko ngbe mi,
Mo nreti aiye tie se ko baje.
3. Egun esusu le ma hu yi mi ka,
Sugbon emi ko ni gbe ‘ra le aiye;
Emi ko wa isimi kan ni aiye,
Tit’, em’ o fi simi l’ aiya Jesu mi.
4. Jek’ idanwo at’ ewu wa l’ ona mi,
Nwon mu k’ orun tubo dun nigb’ aiye pin;
Ibanuje tab’ ohunkohun le de,
Wakati kan lodo Jesu to fun mi.

Tip: double-tap the words (or use ) to show them full screen on a projector or TV.

My melodies

Found another hymn whose tune fits this one? Save it here so you can sing it again.

Sign in to save melodies

Sources: acknowledgements.

Take FaceChrist everywhere

Chat, post, meet people and sell from your phone. Get instant alerts for new messages and matches, plus the Bible offline in seven languages.