YBH 125

Jesu ye; titi aiye

Save
1. Jesu ye; titi aiye
Eru iku ko ba ni mo;
Jesu ye; nitorina
Isa oku ko n ‘ipa mo. - Alleluya!
2. Jesu ye; lat’ oni lo
Iku je ona si iye;
Eyi y’o je ‘ tunu wa
‘Gbat’ akoko iku ba de. - Alleluya!
3. Jesu ye; fun wa l’ O ku;
Nje Tire ni a o ma se;
A o f’okan funfun sin,
A o f’ogo f’Olugbala. - Alleluya!
4. Jesu ye; eyi daju,
Iku at’ ipa okunkun
Ki y’o le ya ni kuro
Ninu ife nla ti Jesu. - Alleluya!
5. Jesu ye; gbogbo ‘joba
L’orun, li aiye, di Tire;
E ja ki a ma tele
Ki a le joba pelu Re. - Alleluya.

Tip: double-tap the words (or use ) to show them full screen on a projector or TV.

My melodies

Found another hymn whose tune fits this one? Save it here so you can sing it again.

Sign in to save melodies

Sources: acknowledgements.

Take FaceChrist everywhere

Chat, post, meet people and sell from your phone. Get instant alerts for new messages and matches, plus the Bible offline in seven languages.