Alleluya! Alleluya!! Alleluya!!!
1. Alleluya! Alleluya!! Alleluya!!!
Ija d’ opin, ogun si tan:
Olugbala jagun molu:
Orin ayo l’ a o ma ko. Alleluya!
Ija d’ opin, ogun si tan:
Olugbala jagun molu:
Orin ayo l’ a o ma ko. Alleluya!
2. Gbogbo ipa n’ iku si lo:
Sugbon Kristi f’ ogun re ka:
Aiye E ho iho ayo - Alleluya!
Sugbon Kristi f’ ogun re ka:
Aiye E ho iho ayo - Alleluya!
3. Ojo meta na ti koja.
O jinde kuro nin’ oku:
E f’ ogo fun Olorun wa. - Alleluya!
O jinde kuro nin’ oku:
E f’ ogo fun Olorun wa. - Alleluya!
4. O d’ ewon orun apadi,
O s’ ilekun orun sile:
E korin iyin ‘segun Re. - Alleluya!
O s’ ilekun orun sile:
E korin iyin ‘segun Re. - Alleluya!
5. Jesu nipa iya t’ O je,
A bo lowo iku titi:
Titi l’ a o si ma yin O. - Alleluya!
A bo lowo iku titi:
Titi l’ a o si ma yin O. - Alleluya!
Tip: double-tap the words (or use ) to show them full screen on a projector or TV.